Arakunrin ẹni ọdun mẹrinlelọgọta, Joseph Ojo, ti wọn fi ẹsun kan pe o dana sun awọn ọmọ marun-un ti iyawo rẹ tuntun bi nilu Ondo, ti ṣalaye nkan to fa igbesẹ rẹ. Ọgbẹni Ojo sọ fun BBC Yoruba ni olu ...